Love Poem (Yoruba Version)

Alayinke mi owon!. (Weekend vibe)
http://teepwords.blogspot.com

Si ololufe mi!,
owunmi lobìrin, oréké lé wà ọmọgé…mo nífé rè tori torùn, tèsè táyá, tojú, tẹ́nu.
Odùn lobìrin lá tokè dé ìsàlè. Tin bá tin ri ẹ áyá mi á ma ṣe gbìgbìgbì asi tun ma la gaarara
Ọlọmọgé Ẹlẹjè tutu
Larìn awọ̀n ọmọ obìrin tí o wa layẹ yìí, iwo ni ọkàn mi yàn
To bá kọ̀ látì fẹ́ mi, aisan ife a gbe mi sanle.
Wá ṣe temi..emi náà fẹ́ ṣe tí ẹ
Awọ̀n sisi pọ ni igbóró tí mo fí yan ẹ
odùn jú gbógbó cranberry juice laye yìí ati ọrún….
Ayinke omo ele mi… jọ́wọ̀ dákun ṣe temi…..
mo fí ásíko yìí ṣélérí fún ẹ wípé nígba ojò, nígba erùn, bí ìle bán jó, bóle bán já, tí ẹ ní mó má ṣé lojokojo
Ti ẹ ni tóòtọ
Ọkọ Ayinke

Written by: Teepwords
For more love, inspirational and life quote, visit

Comments

Popular posts from this blog

Goal.com transfer news

Monkeypox: Delta State Commissioner For Health Visits Suspected Victims(photos)

ADMISSION INTO 2017/2018 PRE-DEGREE PROGRAMME