Alayinke mi owon!. (Weekend vibe) http://teepwords.blogspot.com Si ololufe mi!, owunmi lobìrin, oréké lé wà ọmọgé…mo nífé rè tori torùn, tèsè táyá, tojú, tẹ́nu. Odùn lobìrin lá tokè dé ìsàlè. Tin bá tin ri ẹ áyá mi á ma ṣe gbìgbìgbì asi tun ma la gaarara Ọlọmọgé Ẹlẹjè tutu Larìn awọ̀n ọmọ obìrin tí o wa layẹ yìí, iwo ni ọkàn mi yàn To bá kọ̀ látì fẹ́ mi, aisan ife a gbe mi sanle. Wá ṣe temi..emi náà fẹ́ ṣe tí ẹ Awọ̀n sisi pọ ni igbóró tí mo fí yan ẹ odùn jú gbógbó cranberry juice laye yìí ati ọrún…. Ayinke omo ele mi… jọ́wọ̀ dákun ṣe temi….. mo fí ásíko yìí ṣélérí fún ẹ wípé nígba ojò, nígba erùn, bí ìle bán jó, bóle bán já, tí ẹ ní mó má ṣé lojokojo Ti ẹ ni tóòtọ Ọkọ Ayinke Written by: Teepwords For more love, inspirational and life quote, visit http://teepwords.blogspot.com
Comments
Post a Comment